Brymo – Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)

Download and Play

ALBUM: Brymo - 9: Èsan

Nigerian singer, Brymo releases a brand new hit classic record titled “Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)“.

The song is taken off his newly released body of work titled “9: Èsan Album“.

Download, listen and enjoy!

Brymo – Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)

DOWNLOAD MP3

Lyrics

Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan sureloaded.com
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

RELATED:  Brymo – Beast

Emi ni imole
Olukunkun wo gbo lo
Mo fa lewuya
Mo te lorun pa
Eniyan lasan mi o je
Mo wiwo bi ésan
Emi ni iji to ja lodo
To gboba won lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Okunrin meta debi ti mo n lo

Download and Listen

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *